Oniroyin Ayo Dada
Ile ejo giga Federal High kotu ti o gbo ejo awon ti DSS ko ni ile Oloye Sunday Igboho ni ojo kinni osu keje 2021 ni Abuja ni ojo Ojoru (Wednesday), pa ni ase fun DSS tu won sile ni atimole ti won ma fi se ejo na tan.
Adajo agba Obiora Egwuatu gba lati da awon ti DSS fi esun ti ko ni idi kan, o si pa ni ase pe ki DSS tu won gbogbo won sile.
Sugbon sa, DSS wa nso wipe awon mejo ni won o tu sile l’arin awon mejila ti won ti m’ole, nitori wipe won fi esun kan won wipe awon merin yi mo nipa awon oun ija oloro ti oloye Sunday Igboho fe k’o wo ori ile ede Naijiria.
Esun je iyalenu fun awon agbejo ro awon mejila won yi; won si ti wipe, oun ti o ba gba ni won ma fun lati ri wipe DSS tu awon merin ti o ku sile.
Oruko awon merin na ni yi – Amudat Habitat Babatunde, Abideen Shittu, Jamiu Noah Oyetunji and Bamidele Sunday
Oruko awon mejo ti DSS gba l’ati tu sile ni won yi; Abdulateef Ademola Onaolapo, Tajudeen Irinyole, Diekola Jubril Ademola, Ayobami Donald and Uthman Opeyemi Adelabu. Milion mewa ni ile ejo so wipe ki awon merin won yi fi duro fun eni ikaan kan awon merin yi ki won to le tu won sile.
Kotu ti Abuja yi so wipe milion marun ni won o fi duro fun eni ikaan kan awon mejo yi.
LATEST POSTS
- Afe Babalola gives conditions for truce with Farotimi
- Nigeria Will Become Leading Agricultural Export Nation By 2025 – Tinubu
- Pained by global rush for Farotimi’s bombshell, Afe Babalola sues to seize royalties, block Amazon, others from distributing judicial corruption bestseller
- When an Activist is Hunted by His Activism: A Case of Dele Farotimi
- Nigerian governor’s sister shot by armed robbers dies
SUBSCRIBE TO OUR NEWSLETTER NOW
TEXT AD: To advertise here – Email ad@matazarising.com